Nigerian fast rising gospel artist “Oluwatosin Adebisi” has just released a new single titled “Nigeria Yoo Dara Fun O” featuring another gospel artist “Charity”. As we move closer to the election time, the song was released to encourage Nigerians again about our dear country.
Download and enjoy below ==> https://www.gospeljingle.com/ wp-content/uploads/music/2019/ 02/Oluwatosin_Ft_Charity_-_ Nigeria_Yoo_Dara_Fun_O.mp3
LYRICS
Nigeria Yoo Dara Fun O .
Nigeria yoo dara fun o
Nigeria yoo dara fun o
Into .
Nigeria, ile awon akoni,ile to n san fun wara atoyin ni
Eje ka so wopo kajo tun Nigeria she, kaye soro odi si Nigeria wa mo
Adura temi tire lo nilo yoo o si dara.
Solo .
Ni 1960 aparapo
gbominira,ominira naa da o, oti domi inira
Nkan ko lo dede lori le ede Nigeria yi
Loruko Jesu gbogbo iji dake je.
Solo .
Gbogbo ogun airishe lori awon odo wa
Gbogbo ijoba kijoba k’olorun ko gba joba
A o fe omi inira enife Jesu Olugbala
Olutan isoro ni, oda mi loju agbo adura wa
Gbadura fun Jerusalemu, awon to fe yoo se rere
Jesulemu wa ni Nigeria yi o e, agbadura fun o pe yoo dara fun o
Aamin beeni ko ri o, aamin ati gba leta ayo
Aamin ire gbogbo yoo wole wa wa
Aamin o, hallelujah.
Close
Call:Eje ka gbe laruge o
Resp:Eje ka gbe laruge
Call:I believe there is hope for our Nigeria
Resp:Eje ka gbe laruge
Call:Let’s come together and work in love
Resp:Eje ka gbe laruge
Call:Oti seese fun wa o
Resp:Eje ka gbe laruge
Call:We’re going higher
Resp:Eje ka gbe laruge.
NIGERIA YOO DARA FUN O / 3x
LORUKO JESU NI MO PALASE
YOO DARA FUN O
Artist info
Facebook :Oluwatosin Adebisi.
Instagram :Oluwatosin_timilehin.
Whatsapp/Call :08132187026.